-
1 Kọ́ríńtì 11:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Lákọ̀ọ́kọ́ ná, mo gbọ́ pé nígbà tí ẹ bá kóra jọ nínú ìjọ, ìpínyà máa ń wà láàárín yín; mo sì gbà á gbọ́ dé ìwọ̀n àyè kan. 19 Ó dájú pé àwọn ẹ̀ya ìsìn tún máa wà láàárín yín,+ kí àwọn tí a tẹ́wọ́ gbà nínú yín lè fara hàn kedere.
-