ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 20:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn aninilára ìkookò máa wọlé sáàárín yín,+ wọn ò sì ní fọwọ́ pẹ̀lẹ́ mú agbo, 30 àwọn kan máa dìde láàárín yín, wọ́n á sọ àwọn ọ̀rọ̀ békebèke láti fa àwọn ọmọ ẹ̀yìn sẹ́yìn ara wọn.+

  • 1 Kọ́ríńtì 1:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ohun tí mo ní lọ́kàn ni pé, kálukú yín ń sọ pé: “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ “Èmi jẹ́ ti Kéfà,”* “Èmi jẹ́ ti Kristi.”

  • 1 Tímótì 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́, ọ̀rọ̀ onímìísí* sọ ní kedere pé tó bá yá àwọn kan máa yẹsẹ̀ kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n á máa tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tó ń ṣini lọ́nà àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù,

  • 2 Pétérù 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àmọ́ o, àwọn wòlíì èké tún wà láàárín àwọn èèyàn náà, bí àwọn olùkọ́ èké ṣe máa wà láàárín ẹ̀yin náà.+ Àwọn yìí máa dọ́gbọ́n mú àwọn ẹ̀ya ìsìn tó ń fa ìparun wọlé, wọ́n tiẹ̀ máa sẹ́ ẹni tó rà wọ́n pàápàá,+ wọ́n á sì mú ìparun wá sórí ara wọn ní kíákíá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́