Lúùkù 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹ bá ní ìfaradà, ẹ máa lè pa ẹ̀mí yín mọ́.*+ Róòmù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+
3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+