1 Tímótì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Síbẹ̀, ọmọ bíbí máa dáàbò bò ó,+ tó* bá rọ̀ mọ́ ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́ àti ìjẹ́mímọ́ àti àròjinlẹ̀.*+