Kólósè 4:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ máa gbàdúrà fún wa+ pé kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn fún ọ̀rọ̀ náà, kí a lè kéde àṣírí mímọ́ nípa Kristi, tí mo tìtorí rẹ̀ wà nínú ìdè ẹ̀wọ̀n,+ 4 kí n sì lè kéde rẹ̀ lọ́nà tó ṣe kedere bó ṣe yẹ kí n kéde rẹ̀.
3 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ máa gbàdúrà fún wa+ pé kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn fún ọ̀rọ̀ náà, kí a lè kéde àṣírí mímọ́ nípa Kristi, tí mo tìtorí rẹ̀ wà nínú ìdè ẹ̀wọ̀n,+ 4 kí n sì lè kéde rẹ̀ lọ́nà tó ṣe kedere bó ṣe yẹ kí n kéde rẹ̀.