2 Tẹsalóníkà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi jẹ́ kí ohun tó ń ṣiṣẹ́ ẹ̀tàn kó wọn ṣìnà, kí wọ́n lè gba irọ́ gbọ́,+ 1 Tímótì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́, ọ̀rọ̀ onímìísí* sọ ní kedere pé tó bá yá àwọn kan máa yẹsẹ̀ kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n á máa tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tó ń ṣini lọ́nà àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù,
4 Àmọ́, ọ̀rọ̀ onímìísí* sọ ní kedere pé tó bá yá àwọn kan máa yẹsẹ̀ kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n á máa tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tó ń ṣini lọ́nà àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù,