ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tímótì 5:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Bá àwọn tó sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà+ wí+ níṣojú gbogbo àwùjọ náà, kó lè jẹ́ ìkìlọ̀ fún àwọn yòókù.*

  • Títù 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Torí pé alábòójútó jẹ́ ìríjú Ọlọ́run, kò gbọ́dọ̀ ní ẹ̀sùn lọ́rùn, kó má ṣe jẹ́ ẹni tó ń ṣe tinú ara rẹ̀,+ kó má ṣe jẹ́ ẹni tó ń tètè bínú,+ kó má ṣe jẹ́ ọ̀mùtípara, kó má ṣe jẹ́ oníwà ipá,* kó má sì jẹ́ ẹni tó máa ń wá èrè tí kò tọ́,

  • Títù 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 ẹni tó ń di ọ̀rọ̀ òtítọ́* mú ṣinṣin nínú ọ̀nà tó ń gbà kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́,*+ kó lè fi ẹ̀kọ́ tó ṣàǹfààní*+ gbani níyànjú* kó sì bá àwọn tó ń ṣàtakò wí.+

  • Títù 1:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Òótọ́ ni ẹ̀rí yìí. Torí náà, máa bá wọn wí lọ́nà tó múná, kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára,

  • Títù 2:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Máa sọ nǹkan wọ̀nyí, máa gbani níyànjú, kí o sì máa fi gbogbo àṣẹ tí o ní bá wọn wí.+ Má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan fojú kéré rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́