Ìṣe 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà. Éfésù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kí ẹ lè mọ̀ nípa mi àti bí mo ṣe ń ṣe sí, Tíkíkù,+ arákùnrin ọ̀wọ́n, tó tún jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ gbogbo rẹ̀ fún yín.+ 2 Tímótì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ mo ti rán Tíkíkù+ lọ sí Éfésù.
4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà.
21 Kí ẹ lè mọ̀ nípa mi àti bí mo ṣe ń ṣe sí, Tíkíkù,+ arákùnrin ọ̀wọ́n, tó tún jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ gbogbo rẹ̀ fún yín.+