Hébérù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí ó yẹ kí ẹni tí ohun gbogbo torí rẹ̀ wà, tí ohun gbogbo sì tipasẹ̀ rẹ̀ wà, bí o ti ń mú ọ̀pọ̀ ọmọ wá sínú ògo,+ sọ Olórí Aṣojú ìgbàlà+ wọn di pípé nípasẹ̀ ìjìyà.+ Hébérù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn tí a sì sọ ọ́ di pípé,+ ipasẹ̀ rẹ̀ ni gbogbo àwọn tó ń ṣègbọràn sí i fi máa ní ìgbàlà àìnípẹ̀kun,+
10 Torí ó yẹ kí ẹni tí ohun gbogbo torí rẹ̀ wà, tí ohun gbogbo sì tipasẹ̀ rẹ̀ wà, bí o ti ń mú ọ̀pọ̀ ọmọ wá sínú ògo,+ sọ Olórí Aṣojú ìgbàlà+ wọn di pípé nípasẹ̀ ìjìyà.+
9 Lẹ́yìn tí a sì sọ ọ́ di pípé,+ ipasẹ̀ rẹ̀ ni gbogbo àwọn tó ń ṣègbọràn sí i fi máa ní ìgbàlà àìnípẹ̀kun,+