ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Kí ẹ ṣe àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó máa wà níbẹ̀, kó rí bí ohun* tí màá fi hàn ọ́ gẹ́lẹ́.+

  • Ẹ́kísódù 25:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Rí i pé o ṣe wọ́n bí ohun* tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.+

  • Ẹ́kísódù 26:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Kí o ṣe àgọ́ ìjọsìn náà bí àwòrán tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.+

  • Nọ́ńbà 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Bí wọ́n ṣe ṣe ọ̀pá fìtílà náà nìyí: Wúrà tí wọ́n fi òòlù lù ni wọ́n fi ṣe é; òòlù ni wọ́n fi lù ú+ láti ibi ọ̀pá rẹ̀ débi àwọn ìtànná rẹ̀. Wọ́n ṣe ọ̀pá fìtílà náà bó ṣe rí nínú ìran+ tí Jèhófà fi han Mósè.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́