Sáàmù 102:25-27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Tipẹ́tipẹ́ lo ti fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,Ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.+ 26 Wọ́n á ṣègbé, àmọ́ ìwọ á máa wà nìṣó;Gbogbo wọn á gbó bí aṣọ. Wàá pààrọ̀ wọn bí aṣọ, wọn ò sì ní sí mọ́. 27 Àmọ́ ìwọ kò yí pa dà, àwọn ọdún rẹ kò sì ní dópin láé.+
25 Tipẹ́tipẹ́ lo ti fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,Ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.+ 26 Wọ́n á ṣègbé, àmọ́ ìwọ á máa wà nìṣó;Gbogbo wọn á gbó bí aṣọ. Wàá pààrọ̀ wọn bí aṣọ, wọn ò sì ní sí mọ́. 27 Àmọ́ ìwọ kò yí pa dà, àwọn ọdún rẹ kò sì ní dópin láé.+