Jóòbù 36:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àní, Ọlọ́run tóbi ju bí a ṣe lè mọ̀;+Iye àwọn ọdún rẹ̀ kọjá òye wa.*+ Málákì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Torí èmi ni Jèhófà; èmi kì í yí pa dà.*+ Ẹ̀yin sì ni ọmọ Jékọ́bù; ẹ kò tíì pa run. Jémíìsì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé wá láti òkè,+ ó ń wá látọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá,+ ẹni tí kì í yí pa dà, tí kì í sì í sún kiri bí òjìji.*+
17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé wá láti òkè,+ ó ń wá látọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá,+ ẹni tí kì í yí pa dà, tí kì í sì í sún kiri bí òjìji.*+