Ẹ́kísódù 30:17-19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 18 “Kí o fi bàbà ṣe bàsíà kan pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ fún wíwẹ̀;+ kí o gbé e sáàárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, kí o sì bu omi sínú rẹ̀.+ 19 Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ wọn àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀.+
17 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 18 “Kí o fi bàbà ṣe bàsíà kan pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀ fún wíwẹ̀;+ kí o gbé e sáàárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, kí o sì bu omi sínú rẹ̀.+ 19 Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ wọn àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀.+