Lúùkù 22:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà, lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá,*+ tí a máa dà jáde nítorí yín.+ 1 Tímótì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí Ọlọ́run kan ló wà+ àti alárinà kan+ láàárín Ọlọ́run àtàwọn èèyàn,+ ọkùnrin kan, Kristi Jésù,+ Hébérù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì Hébérù 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 àti Jésù alárinà+ májẹ̀mú tuntun + àti ẹ̀jẹ̀ tí a wọ́n, tó ń sọ̀rọ̀ lọ́nà tó dáa ju ẹ̀jẹ̀ Ébẹ́lì lọ.+
20 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà, lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá,*+ tí a máa dà jáde nítorí yín.+
22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì
24 àti Jésù alárinà+ májẹ̀mú tuntun + àti ẹ̀jẹ̀ tí a wọ́n, tó ń sọ̀rọ̀ lọ́nà tó dáa ju ẹ̀jẹ̀ Ébẹ́lì lọ.+