Kólósè 2:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan dá yín lẹ́jọ́ lórí ohun tí ẹ̀ ń jẹ àti ohun tí ẹ̀ ń mu+ tàbí lórí àjọyọ̀ kan tí ẹ ṣe tàbí òṣùpá tuntun+ tàbí sábáàtì.+ 17 Àwọn nǹkan yẹn jẹ́ òjìji àwọn ohun tó ń bọ̀,+ àmọ́ Kristi ni ohun gidi náà.+
16 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan dá yín lẹ́jọ́ lórí ohun tí ẹ̀ ń jẹ àti ohun tí ẹ̀ ń mu+ tàbí lórí àjọyọ̀ kan tí ẹ ṣe tàbí òṣùpá tuntun+ tàbí sábáàtì.+ 17 Àwọn nǹkan yẹn jẹ́ òjìji àwọn ohun tó ń bọ̀,+ àmọ́ Kristi ni ohun gidi náà.+