Léfítíkù 16:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Èyí máa jẹ́ àṣẹ tí ẹ ó máa pa mọ́ títí lọ,+ láti ṣe ètùtù fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́ẹ̀kan lọ́dún+ torí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn.” Torí náà, ó ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.
34 Èyí máa jẹ́ àṣẹ tí ẹ ó máa pa mọ́ títí lọ,+ láti ṣe ètùtù fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́ẹ̀kan lọ́dún+ torí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn.” Torí náà, ó ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.