2 Pétérù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí ì bá sàn kí wọ́n má mọ ọ̀nà òdodo lọ́nà tó péye ju pé lẹ́yìn tí wọ́n ti mọ̀ ọ́n kí wọ́n yí pa dà kúrò nínú àṣẹ mímọ́ tí wọ́n ti gbà.+
21 Torí ì bá sàn kí wọ́n má mọ ọ̀nà òdodo lọ́nà tó péye ju pé lẹ́yìn tí wọ́n ti mọ̀ ọ́n kí wọ́n yí pa dà kúrò nínú àṣẹ mímọ́ tí wọ́n ti gbà.+