ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 12:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Bí àpẹẹrẹ, ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ọmọ èèyàn máa rí ìdáríjì;+ àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, kò ní rí ìdáríjì, àní, nínú ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí èyí tó ń bọ̀.+

  • Hébérù 6:4-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí ní ti àwọn tí a ti là lóye rí,+ tí wọ́n ti tọ́ ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ti ọ̀run wò, tí wọ́n sì ti ní ìpín nínú ẹ̀mí mímọ́, 5 tí wọ́n ti tọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ ọ̀rọ̀ àtàtà wò àti agbára ètò àwọn nǹkan tó ń bọ̀,* 6 àmọ́ tí wọ́n yẹsẹ̀,+ kò ṣeé ṣe láti tún mú wọn sọ jí kí wọ́n lè ronú pìwà dà, torí ṣe ni wọ́n tún kan Ọmọ Ọlọ́run mọ́gi* fún ara wọn, wọ́n sì dójú tì í ní gbangba.+

  • 1 Jòhánù 5:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Tí ẹnikẹ́ni bá rí arákùnrin rẹ̀ tó ń dẹ́ṣẹ̀ tí kò yẹ fún ikú, ó máa gbàdúrà, Ọlọ́run sì máa fún un ní ìyè,+ àní, fún àwọn tí kò dẹ́ṣẹ̀ tó yẹ fún ikú. Ẹ̀ṣẹ̀ kan wà tó yẹ fún ikú.+ Irú ẹ̀ṣẹ̀ yẹn ni mi ò sọ fún un pé kó gbàdúrà nípa rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́