Éfésù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó ti la ojú inú* yín, kí ẹ lè mọ ìrètí tí ó pè yín láti ní, kí ẹ lè mọ ọrọ̀ ológo tó fẹ́ fi ṣe ogún fún àwọn ẹni mímọ́+ Hébérù 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+
18 Ó ti la ojú inú* yín, kí ẹ lè mọ ìrètí tí ó pè yín láti ní, kí ẹ lè mọ ọrọ̀ ológo tó fẹ́ fi ṣe ogún fún àwọn ẹni mímọ́+
26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+