Jẹ́nẹ́sísì 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, ó kúrò níbẹ̀ lọ sí agbègbè olókè tó wà ní ìlà oòrùn Bẹ́tẹ́lì,+ ó pa àgọ́ rẹ̀ síbẹ̀, Bẹ́tẹ́lì wà ní ìwọ̀ oòrùn àgọ́ náà, Áì+ sì wà ní ìlà oòrùn. Ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pe orúkọ Jèhófà.+
8 Lẹ́yìn náà, ó kúrò níbẹ̀ lọ sí agbègbè olókè tó wà ní ìlà oòrùn Bẹ́tẹ́lì,+ ó pa àgọ́ rẹ̀ síbẹ̀, Bẹ́tẹ́lì wà ní ìwọ̀ oòrùn àgọ́ náà, Áì+ sì wà ní ìlà oòrùn. Ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pe orúkọ Jèhófà.+