Jẹ́nẹ́sísì 47:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ísírẹ́lì wá sọ pé: “Búra fún mi.” Ó sì búra fún un.+ Ísírẹ́lì sì tẹrí ba níbi ìgbèrí ibùsùn+ rẹ̀.