Jẹ́nẹ́sísì 50:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 ‘Bàbá mi mú kí n búra,+ ó ní: “Wò ó! Mi ò ní pẹ́ kú.+ Kí o sin mí sí ibi ìsìnkú+ mi tí mo gbẹ́ ní ilẹ̀ Kénáánì.”+ Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n lọ sin bàbá mi, màá sì pa dà lẹ́yìn náà.’”
5 ‘Bàbá mi mú kí n búra,+ ó ní: “Wò ó! Mi ò ní pẹ́ kú.+ Kí o sin mí sí ibi ìsìnkú+ mi tí mo gbẹ́ ní ilẹ̀ Kénáánì.”+ Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n lọ sin bàbá mi, màá sì pa dà lẹ́yìn náà.’”