Sáàmù 8:4-6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tí o fi ń fi í sọ́kànÀti ọmọ aráyé tí o fi ń tọ́jú rẹ̀?+ 5 O mú kó rẹlẹ̀ díẹ̀ ju àwọn ẹni bí Ọlọ́run,*O sì fi ògo àti ọlá ńlá dé e ládé. 6 O fún un ní àṣẹ lórí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ;+O ti fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀:
4 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tí o fi ń fi í sọ́kànÀti ọmọ aráyé tí o fi ń tọ́jú rẹ̀?+ 5 O mú kó rẹlẹ̀ díẹ̀ ju àwọn ẹni bí Ọlọ́run,*O sì fi ògo àti ọlá ńlá dé e ládé. 6 O fún un ní àṣẹ lórí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ;+O ti fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀: