Ẹ́kísódù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Obìnrin náà lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Nígbà tó rí bí ọmọ náà ṣe rẹwà tó, ó gbé e pa mọ́ fún oṣù mẹ́ta.+
2 Obìnrin náà lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Nígbà tó rí bí ọmọ náà ṣe rẹwà tó, ó gbé e pa mọ́ fún oṣù mẹ́ta.+