Ìṣe 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lákòókò yẹn, wọ́n bí Mósè, Ọlọ́run sì fún un lẹ́wà gan-an.* Wọ́n fi oṣù mẹ́ta tọ́jú rẹ̀* ní ilé bàbá rẹ̀.+ Hébérù 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìgbàgbọ́ mú kí àwọn òbí Mósè gbé e pa mọ́ fún oṣù mẹ́ta lẹ́yìn tí wọ́n bí i,+ torí wọ́n rí i pé ọmọ kékeré náà rẹwà,+ wọn ò sì bẹ̀rù àṣẹ ọba.+
20 Lákòókò yẹn, wọ́n bí Mósè, Ọlọ́run sì fún un lẹ́wà gan-an.* Wọ́n fi oṣù mẹ́ta tọ́jú rẹ̀* ní ilé bàbá rẹ̀.+
23 Ìgbàgbọ́ mú kí àwọn òbí Mósè gbé e pa mọ́ fún oṣù mẹ́ta lẹ́yìn tí wọ́n bí i,+ torí wọ́n rí i pé ọmọ kékeré náà rẹwà,+ wọn ò sì bẹ̀rù àṣẹ ọba.+