Òwe 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ṣé ó yẹ kí ìsun omi rẹ tú síta,Kí ìṣàn omi rẹ sì tú sí àwọn ojúde ìlú?+ Òwe 5:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí náà, ọmọ mi, kí nìdí tí wàá fi jẹ́ kí obìnrin oníwàkiwà* gbà ọ́ lọ́kànTàbí tí wàá fi gbá àyà obìnrin oníṣekúṣe* mọ́ra?+ Mátíù 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+
20 Torí náà, ọmọ mi, kí nìdí tí wàá fi jẹ́ kí obìnrin oníwàkiwà* gbà ọ́ lọ́kànTàbí tí wàá fi gbá àyà obìnrin oníṣekúṣe* mọ́ra?+
28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+