-
1 Kọ́ríńtì 9:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+
-
-
1 Kọ́ríńtì 10:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ẹ wo Ísírẹ́lì lọ́nà ti ara: Ǹjẹ́ àwọn tó ń jẹ ohun tí a fi rúbọ kì í ṣe alájọpín pẹ̀lú pẹpẹ?+
-