Róòmù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ máa ṣàjọpín nǹkan pẹ̀lú àwọn ẹni mímọ́ kí wọ́n lè rí ohun tí wọ́n nílò.+ Ẹ máa ṣe aájò àlejò.+