Ẹ́kísódù 31:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó jẹ́ àmì tó máa wà pẹ́ títí láàárín èmi àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ torí ọjọ́ mẹ́fà ni Jèhófà fi dá ọ̀run àti ayé, ó wá sinmi ní ọjọ́ keje, ara sì tù ú.’”+
17 Ó jẹ́ àmì tó máa wà pẹ́ títí láàárín èmi àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ torí ọjọ́ mẹ́fà ni Jèhófà fi dá ọ̀run àti ayé, ó wá sinmi ní ọjọ́ keje, ara sì tù ú.’”+