Kólósè 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ Kristi máa gbé inú yín lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú gbogbo ọgbọ́n. Ẹ máa kọ́ ara yín, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú* pẹ̀lú àwọn sáàmù,+ ìyìn sí Ọlọ́run, àwọn orin ẹ̀mí tí à ń fi ìmoore* kọ, kí ẹ máa kọrin sí Jèhófà* nínú ọkàn yín.+
16 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ Kristi máa gbé inú yín lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú gbogbo ọgbọ́n. Ẹ máa kọ́ ara yín, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú* pẹ̀lú àwọn sáàmù,+ ìyìn sí Ọlọ́run, àwọn orin ẹ̀mí tí à ń fi ìmoore* kọ, kí ẹ máa kọrin sí Jèhófà* nínú ọkàn yín.+