Jẹ́nẹ́sísì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Obìnrin náà wá rí i pé èso igi náà dára fún jíjẹ, ó dùn-ún wò, àní, igi náà wuni. Ló bá mú lára èso rẹ̀, ó sì jẹ ẹ́.+ Lẹ́yìn náà, ó fún ọkọ rẹ̀ lára èso náà nígbà tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.+ 1 Jòhánù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé.
6 Obìnrin náà wá rí i pé èso igi náà dára fún jíjẹ, ó dùn-ún wò, àní, igi náà wuni. Ló bá mú lára èso rẹ̀, ó sì jẹ ẹ́.+ Lẹ́yìn náà, ó fún ọkọ rẹ̀ lára èso náà nígbà tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.+
16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé.