Róòmù 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+ 1 Kọ́ríńtì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 nítorí ẹ ṣì jẹ́ ẹni ti ara.+ Nígbà tí owú àti wàhálà wà láàárín yín, ṣé ẹ kì í ṣe ẹni ti ara ni,+ ṣé ẹ kì í sì í ṣe bí àwọn èèyàn ayé ni?
13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+
3 nítorí ẹ ṣì jẹ́ ẹni ti ara.+ Nígbà tí owú àti wàhálà wà láàárín yín, ṣé ẹ kì í ṣe ẹni ti ara ni,+ ṣé ẹ kì í sì í ṣe bí àwọn èèyàn ayé ni?