Róòmù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín wà láìsí ẹ̀tàn.*+ Ẹ kórìíra ohun búburú;+ ẹ rọ̀ mọ́ ohun rere. 1 Tímótì 5:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Má ṣe fi ọ̀rọ̀ líle bá àgbà ọkùnrin wí.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí o pàrọwà fún un bíi bàbá, pàrọwà fún àwọn ọ̀dọ́kùnrin bí ọmọ ìyá, 2 àwọn àgbà obìnrin bí ìyá, àwọn ọ̀dọ́bìnrin bí ọmọ ìyá, pẹ̀lú gbogbo ìwà mímọ́.
5 Má ṣe fi ọ̀rọ̀ líle bá àgbà ọkùnrin wí.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí o pàrọwà fún un bíi bàbá, pàrọwà fún àwọn ọ̀dọ́kùnrin bí ọmọ ìyá, 2 àwọn àgbà obìnrin bí ìyá, àwọn ọ̀dọ́bìnrin bí ọmọ ìyá, pẹ̀lú gbogbo ìwà mímọ́.