1 Kọ́ríńtì 11:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Síbẹ̀, nígbà tí a bá dá wa lẹ́jọ́, Jèhófà* ló ń bá wa wí,+ kí a má bàa dá wa lẹ́bi pẹ̀lú ayé.+