2 Kọ́ríńtì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìpọ́njú* náà jẹ́ fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára, ó ń yọrí sí ògo fún wa, ògo tí ó tóbi* gan-an, tí ó sì jẹ́ ti ayérayé;+ 1 Tẹsalóníkà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó yẹ Ọlọ́run,+ ẹni tó ń pè yín sí Ìjọba+ àti ògo rẹ̀.+
17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìpọ́njú* náà jẹ́ fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára, ó ń yọrí sí ògo fún wa, ògo tí ó tóbi* gan-an, tí ó sì jẹ́ ti ayérayé;+