Àìsáyà 53:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+ Róòmù 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Má ṣe jẹ́ kí ibi ṣẹ́gun rẹ, àmọ́ máa fi ire ṣẹ́gun ibi.+
7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+