Òwe 3:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 O ò ní bẹ̀rù àjálù òjijì+Tàbí ìjì tó ń bọ̀ lórí àwọn ẹni burúkú.+ Fílípì 1:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 ẹ ò sì jẹ́ kí àwọn tó ń ta kò yín kó jìnnìjìnnì bá yín lọ́nàkọnà. Èyí jẹ́ àmì ìparun+ fún wọn, àmọ́ ó jẹ́ ti ìgbàlà fún yín;+ ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ló sì ti wá.
28 ẹ ò sì jẹ́ kí àwọn tó ń ta kò yín kó jìnnìjìnnì bá yín lọ́nàkọnà. Èyí jẹ́ àmì ìparun+ fún wọn, àmọ́ ó jẹ́ ti ìgbàlà fún yín;+ ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ló sì ti wá.