2 Kọ́ríńtì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí a mọ̀ pé tí ilé wa ní ayé bá wó,*+ ìyẹn àgọ́ yìí, Ọlọ́run máa fún wa ní ilé míì, ilé tí a kò fi ọwọ́ kọ́,+ tó jẹ́ ti ayérayé ní ọ̀run.
5 Nítorí a mọ̀ pé tí ilé wa ní ayé bá wó,*+ ìyẹn àgọ́ yìí, Ọlọ́run máa fún wa ní ilé míì, ilé tí a kò fi ọwọ́ kọ́,+ tó jẹ́ ti ayérayé ní ọ̀run.