2 Pétérù 1:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ mo rí i pé ó dáa, tí mo bá ṣì wà nínú àgọ́* yìí,+ láti máa rán yín létí kí n lè ta yín jí,+ 14 bí mo ṣe mọ̀ pé màá tó bọ́ àgọ́ mi kúrò, bí Olúwa wa Jésù Kristi ṣe jẹ́ kí n mọ̀ kedere.+
13 Àmọ́ mo rí i pé ó dáa, tí mo bá ṣì wà nínú àgọ́* yìí,+ láti máa rán yín létí kí n lè ta yín jí,+ 14 bí mo ṣe mọ̀ pé màá tó bọ́ àgọ́ mi kúrò, bí Olúwa wa Jésù Kristi ṣe jẹ́ kí n mọ̀ kedere.+