Lúùkù 22:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 mo sì bá yín dá májẹ̀mú fún ìjọba kan, bí Baba mi ṣe bá mi dá májẹ̀mú,+ 30 kí ẹ lè máa jẹ, kí ẹ sì máa mu ní tábìlì mi nínú Ìjọba mi,+ kí ẹ sì jókòó lórí ìtẹ́+ láti ṣèdájọ́ ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.+ Jòhánù 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nínú ilé Baba mi, ọ̀pọ̀ ibùgbé* ló wà. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ǹ bá ti sọ fún yín, torí pé mò ń lọ kí n lè pèsè ibì kan sílẹ̀ fún yín.+ Gálátíà 3:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Yàtọ̀ síyẹn, bí ẹ bá jẹ́ ti Kristi, ẹ jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù lóòótọ́,+ ajogún+ nípasẹ̀ ìlérí.+
29 mo sì bá yín dá májẹ̀mú fún ìjọba kan, bí Baba mi ṣe bá mi dá májẹ̀mú,+ 30 kí ẹ lè máa jẹ, kí ẹ sì máa mu ní tábìlì mi nínú Ìjọba mi,+ kí ẹ sì jókòó lórí ìtẹ́+ láti ṣèdájọ́ ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.+
2 Nínú ilé Baba mi, ọ̀pọ̀ ibùgbé* ló wà. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ǹ bá ti sọ fún yín, torí pé mò ń lọ kí n lè pèsè ibì kan sílẹ̀ fún yín.+