1 Pétérù 3:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bẹ́ẹ̀ ló ṣe lọ wàásù fún àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,+ 20 àwọn tó ṣàìgbọràn nígbà tí Ọlọ́run ń fi sùúrù dúró* ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ lákòókò tí wọ́n ń kan ọkọ̀ áàkì,+ tí a fi gba àwọn èèyàn díẹ̀ là nígbà ìkún omi, ìyẹn ọkàn* mẹ́jọ.+
19 Bẹ́ẹ̀ ló ṣe lọ wàásù fún àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,+ 20 àwọn tó ṣàìgbọràn nígbà tí Ọlọ́run ń fi sùúrù dúró* ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ lákòókò tí wọ́n ń kan ọkọ̀ áàkì,+ tí a fi gba àwọn èèyàn díẹ̀ là nígbà ìkún omi, ìyẹn ọkàn* mẹ́jọ.+