-
Fílípì 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, bí ẹ ṣe ń ṣègbọràn ní gbogbo ìgbà, tí kì í ṣe nígbà tí mo bá wà lọ́dọ̀ yín nìkan, àmọ́ ní báyìí, ẹ túbọ̀ ń ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà tí mi ò sí lọ́dọ̀ yín, ẹ máa ṣiṣẹ́ ìgbàlà yín yọrí pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì.
-