Júùdù 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn èèyàn yìí máa ń ráhùn,+ wọ́n máa ń ṣàròyé nípa bí nǹkan ṣe rí fún wọn, ìfẹ́ inú wọn ni wọ́n máa ń ṣe,+ wọ́n ń fọ́nnu, wọ́n sì ń fi ọ̀rọ̀ dídùn pọ́n* àwọn ẹlòmíì torí àǹfààní tí wọ́n máa rí.+
16 Àwọn èèyàn yìí máa ń ráhùn,+ wọ́n máa ń ṣàròyé nípa bí nǹkan ṣe rí fún wọn, ìfẹ́ inú wọn ni wọ́n máa ń ṣe,+ wọ́n ń fọ́nnu, wọ́n sì ń fi ọ̀rọ̀ dídùn pọ́n* àwọn ẹlòmíì torí àǹfààní tí wọ́n máa rí.+