2 Pétérù 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ kàǹkà-kàǹkà tí kò nítumọ̀. Wọ́n ń fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara+ àti ìwà àìnítìjú* tan àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ ṣomi mu.+
18 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ kàǹkà-kàǹkà tí kò nítumọ̀. Wọ́n ń fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara+ àti ìwà àìnítìjú* tan àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ ṣomi mu.+