Jóẹ́lì 2:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀+Kí ọjọ́ ńlá Jèhófà tó ń bani lẹ́rù tó dé.+ Sefanáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọjọ́ ńlá Jèhófà sún mọ́lé!+ Ó sún mọ́lé, ó sì ń yára bọ̀ kánkán!*+ Ìró ọjọ́ Jèhófà korò.+ Akíkanjú ológun máa figbe ta níbẹ̀.+
14 Ọjọ́ ńlá Jèhófà sún mọ́lé!+ Ó sún mọ́lé, ó sì ń yára bọ̀ kánkán!*+ Ìró ọjọ́ Jèhófà korò.+ Akíkanjú ológun máa figbe ta níbẹ̀.+