Sáàmù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn olódodo ni yóò jogún ayé,+Wọn yóò sì máa gbé inú rẹ̀ títí láé.+ Mátíù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Kì í ṣe gbogbo ẹni tó ń pè mí ní, ‘Olúwa, Olúwa,’ ló máa wọ Ìjọba ọ̀run, àmọ́ ẹni tó ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run nìkan ló máa wọ̀ ọ́.+ Jòhánù 6:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Torí ìfẹ́ Baba mi ni pé kí gbogbo ẹni tó mọ Ọmọ, tó sì ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ màá sì jí i dìde+ ní ọjọ́ ìkẹyìn.”
21 “Kì í ṣe gbogbo ẹni tó ń pè mí ní, ‘Olúwa, Olúwa,’ ló máa wọ Ìjọba ọ̀run, àmọ́ ẹni tó ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run nìkan ló máa wọ̀ ọ́.+
40 Torí ìfẹ́ Baba mi ni pé kí gbogbo ẹni tó mọ Ọmọ, tó sì ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ màá sì jí i dìde+ ní ọjọ́ ìkẹyìn.”