Jòhánù 5:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ẹnikẹ́ni tó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tó sì gba Ẹni tó rán mi gbọ́, ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ a ò sì ní dá a lẹ́jọ́, àmọ́ ó ti tinú ikú bọ́ sínú ìyè.+ Róòmù 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí òfin ẹ̀mí tó ń fúnni ní ìyè nínú Kristi Jésù ti dá ọ sílẹ̀+ kúrò lọ́wọ́ òfin ẹ̀ṣẹ̀ àti ti ikú.
24 Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ẹnikẹ́ni tó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tó sì gba Ẹni tó rán mi gbọ́, ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ a ò sì ní dá a lẹ́jọ́, àmọ́ ó ti tinú ikú bọ́ sínú ìyè.+
2 Nítorí òfin ẹ̀mí tó ń fúnni ní ìyè nínú Kristi Jésù ti dá ọ sílẹ̀+ kúrò lọ́wọ́ òfin ẹ̀ṣẹ̀ àti ti ikú.