Róòmù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín wà láìsí ẹ̀tàn.*+ Ẹ kórìíra ohun búburú;+ ẹ rọ̀ mọ́ ohun rere.