ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Jòhánù 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ẹ̀yin ọmọdé, wákàtí ìkẹyìn nìyí, bí ẹ sì ṣe gbọ́ pé aṣòdì sí Kristi ń bọ̀,+ kódà ọ̀pọ̀ aṣòdì sí Kristi ló ti fara hàn báyìí,+ ìyẹn sì jẹ́ ká mọ̀ pé wákàtí ìkẹyìn nìyí lóòótọ́.

  • 1 Jòhánù 2:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ta ni òpùrọ́ tí kì í bá ṣe ẹni tó sọ pé Jésù kọ́ ni Kristi?+ Ẹni yìí ni aṣòdì sí Kristi,+ ẹni tó sẹ́ Baba àti Ọmọ.

  • 1 Jòhánù 4:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àmọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ onímìísí tí kò bá fi hàn pé Jésù wá, kò wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+ Bákan náà, ọ̀rọ̀ yìí ni aṣòdì sí Kristi mí sí, ẹni tí ẹ gbọ́ pé ó ń bọ̀,+ ó sì ti wà ní ayé báyìí.+

  • Júùdù 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ìdí ni pé àwọn kan ti yọ́ wọlé sí àárín yín, àwọn tí Ìwé Mímọ́ ti sọ tipẹ́tipẹ́ pé ìdájọ́ ń bọ̀ sórí wọn. Wọn ò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run wa ṣe àwáwí láti máa hu ìwà àìnítìjú,*+ wọ́n sì kọ Jésù Kristi, ẹnì kan ṣoṣo tó ni wá,* tó sì jẹ́ Olúwa wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́