Hébérù 10:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Torí náà, ẹ má sọ ìgboyà yín* nù, èyí tí a máa torí rẹ̀ fún yín ní èrè tó kún rẹ́rẹ́.+